Orin 444
‘K’ On tó de, ‘---jẹ k’ọ̀rọ yi
Till he come, O let the words
- cr ‘K’ On tó de, ‘---jẹ k’ọ̀rọ yi
Ma dún titi l’eti rẹ;
Jẹ ki sa diẹ t’o kù
Hàn gbangba daju fun ọ;
f Ronu b’ọrun on ile
di Ti d‘ẹ̀hin gbat’ ‘O ba de.’ - p Gbat’ awọn ti a fẹràn
Bọ́ si ‘simi wọn l’oke,
T’o jọ pe aiye wa pin,
Ti adùn rẹ̀ si korò;
di Ẹ dakun, ẹ má b’ọhun,
cr Kiki ‘k’ On to de’ ṣá ni. - mp Ibanujẹ yi wa ka;
A ha fẹ k’o dinku bi?
Gbogbo ẹrù ipọnju,
Gbogbo òfo aiye yi,
Iku, ọ̀fọ aiye yi,
p Nsọ jẹjẹ pe, ‘K’ On t’o de.’ - mf Wo tabil’ ifẹ t’a tẹ́,
Mu waini, si j’akara;
‘Ranti didun, ---k’ Oluwa
To pè wa s’onjẹ ọrun;
p ‘Mì kat’ aiye, ‘m’ l’ọrun,
cr Nwọn pinyà tit’ ‘On fi de.´ Amin.