Anglican Hymnal
This is Jehovah’s great command
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 446: This is Jehovah’s great command
Eyi l’ ase nla Jehofa
Hymn:
446
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Baptismu Agba
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Eyi l’ aṣẹ nla Jehofa,
Yio wà titi lai;
Ẹlẹṣẹ b’ iwọ at’ emi,
K’ a tun gbogbo wa bi.
p
Okunkun y’o jẹ ipa wa,
B’ a wà ninu ẹ̀ṣẹ;
A ki o rì ijọba Rẹ̀,
Bi a kò d’ atunbi.
Bi baptisi wa jẹ ‘gbarun,
Asan ni gbogbo rẹ;
Eyi kò lè w’ẹ̀ṣẹ wa nù,
Bi a kò tun wa bi.
Wò iṣẹ wère ti à nṣe,
Kò ni iranwọ Rẹ̀;
Nwọn kò s’ ọkàn wa di ọtun,
B’ awa kò d’ atunbi.
f
Lọ kuro ninu ẹ̀ṣẹ rẹ
cr
Ja ẹ̀wọn Eṣu nù;
f
Gbà Kristi gbọ́ tọkàntọkàn
ff
Iwọ o d’ atunbi. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites