Hymn 85: Behold Christ the Lord hath come

O de, Kristi Oluwa

  1. O de, kristi Oluwa ,
    Lat’ ibugbe Rẹ̀ l’ ọrun,
    Lat’ itẹ alafia
    O wá si aginju wa.

  2. Alade Alafia
    De, lati ru ‘pọnju wa,
    O de, lati f’ imọlẹ
    Le okùn oru wa lọ. Amin.