Hymn 596: Thou Sun of Righteousness arise

Orun ododo, jowo la

  1. Orùn Ododo, jọwọ là,
    Ma ràn jẹjẹ lori Sion,
    Tu òkunkun oju wa ka,
    Jẹ k’ọkàn wa k’o ji si ‘yè.

  2. Jẹ k’ore-ọfẹ bà le wa,
    B’iri ọrun, b’ọpọ ojo;
    K’a lè mọ p’On l’Ọrẹ wa san,
    K’a le pè ‘gbala ni tiwa.