Hymn 579: Much as the stars my sins abound

Ese mi po bi irawo

  1. mp Ẹṣẹ mi pọ̀ bi irawọ,
    Bi yanrìn let’ okun;
    Ṣugbọn iyọnu Ọlọrun,
    O papọju bẹ lọ̀.

  2. Manase, Paul, on Magdalen
    Iwọ dariji wọn:
    Mo ti ka, mo si gbagbọ pe,
    O ti darijì mi. Amin.