Hymn 567: In the house of our God

Ni ile Olorun

  1. mf Ni ile Ọlọrun,
    Ẹ yìn orukọ Rẹ̀;
    Ati laiye gbogbo
    Ẹ f’ agbara Rẹ̀ hàn;
    Ki ohun gbogbo t’o l’ẹmí.
    Ki nwọn yìn Ọlọrun ifẹ. Amin.