Hymn 546: Upon what was planted

Si ohun ti a gbin

  1. Si ohun ti a gbìn,
    Sẹ iri ‘bukun Rẹ;
    Agbara ni Tirẹ,
    Lati mu k’o dagbà:
    Jẹ ki ‘korè k’o pọ̀ si I,
    Iyin a jẹ Tirẹ nikan. Amin.