Hymn 484: Be present at our table, Lord

Wa, ba wa jeun, Oluwa

I
mf Wá, ba wa jẹun, Oluwa,
Jẹ k’ a ma yìn orukọ Rẹ;
cr Wa busi onjẹ wa; si jẹ
K’ a lè ba O jẹun l’ọrun. Amin.

ADURA TI O KẸHIN ONJẸ

II
f A f’ọpẹ fun Ọ, Oluwa,
Fun onjẹ wa, at’ ẹbùn mi;
di Fi onjẹ ọrun b’ ọkàn wa,
cr Onjẹ iyè lat’ òke wa. Amin.