Hymn 469: The sun shines its light;

Orun tanmole

  1. mf Orun tanmọlẹ;
    Orun ti sa lọ;
    Gbogbo ‘ro àyọ l’o ndún kakiri.

  2. Orọ̀ dùn mọ mi,
    Ọpẹ f’ Ọlọrun:
    Oluṣọ ti nṣọ mi nigba mo sùn.

  3. Gbọ́, ‘gba mo ba nde,
    Orin ‘yin mi yi
    K’ ọkàn mi k’o ba ọ duro loni. Amin.