Hymn 454: Come! Holy Spirit come

Emi Olorun wa

  1. mf Ẹmi Ọlọrun wa,
    Baptis’ awọn wọnyi:
    Ba wọn da majẹmu mimọ́,
    Wẹ̀ wọn kuro l’ẹ̀ṣẹ.

  2. f Fọ ‘pa Eọu tutu,
    cr Wẹ̀ wọn ‘nu ẹjẹ Rẹ;
    Baba, Ọmọ, Ẹmi Mimọ́,
    Sọ wọn di Ọmọ Rẹ. Amin.