Hymn 452: Come, Holy Ghost, descend from high,

Wa, Emi Mimo, sokale

  1. mf Wa, Ẹmi Mimọ, sọkalẹ,
    Onibaptisi ọkàn wa,
    M’edidi majẹmu Rẹ wa,
    K’o si ṣe ẹ̀ri omi yi.

  2. Tu agbara nla Rẹ jade,
    K’o si wọ́n ẹ̀jẹ etutu;
    Ki Baba, Ọmọ, at’Ẹmi,
    Jọ sọ (wọn) ọ d’ ọmọ Ọlọrun. Amin.