- f Iyin ainipẹ̀kun,
Ni ka fun Baba;
Iyin ainipẹkun,
Ni ka fun Ọmọ;
Iyin ainipẹkun,
Ni ka fun Ẹmi;
Iyin ainipẹkun,
Fun Mẹtalọkan.;
- f F’ iyin ainipẹkun
Fun ifẹ Baba,
F’iyin ainipẹkun
Fun ifẹ Ọmọ,
F’ iyin ainipẹkun,
Fun ifẹ Ẹmì,
F’ iyin ainipẹkun
Fun Mẹtalọkan. Amin.