- f A bẹ̀, a fẹ fi Ọ
Ọjọ ‘simi rere
Gbogbo ọ̀sẹ ama wipe
Iwọ o ti pẹ to?
- O kọ wa pe Kristi
f Jinde ninu okù;
Gbogbo ọsẹ ama wipe,
Iwo o ti pẹ to!
- O sọ t’ ajinde wa
Gẹgẹ bi ti Jesu;
Gbogbo ọsẹ ama wipe,
Iwọ o ti pe to!
- mf Iwọ sọ t’ isimi
T’ ilu alafia;
T’ ibukun enia mimọ́
Iwọ o ti pẹ to! Amin.