- mp Ero di/dun kan / nsọ
S’ọkàn / mi fi / rifi / ri, -
Mo sunmọ ‘le / mi lo/ni,
Jù bi / mo ti / sunmọ / ri.
- cr Mo sunmọ / ‘tẹ́ nla / ni,
Mo sunm’ / okun / krista/li,
Mo sunmọ / ‘le Ba/ba,
Nibiti / ‘bugbe / pupọ / wa.
- p Mo sunm’ o/pin ẹ/mi,
T’ a / sọ ẹ/rù ka/le;
T’ a gb’ agbele/bu silẹ,
T’ a / si bẹ/rẹ gb’a/de.
- p Lagbedeme/ji ey/i,
Ni / ‘ṣan-o/mi du/du;
cr Ti a o là kọ/ja dan/dan.
K’a / to de / ‘mọlẹ / na.
- cr Jesu, jo / ṣe mi / pè,
Sọ ‘gba/gbọ mi / di li/le;
Jẹ ki nmọ̀ p’O / sunmọ /mi,
Le/ti be/be i/ku.
- p Ki mmọ p’O / sunmọ / mi,
Gba / mba njin / si kò/to;
O le jẹ pe mo / nsunmọ/le,
Sunmọ / jù bi / mo ti / rò. Amin.