Hymn 119: The heathens perish; day by day

Keferi nsegbe lojojo

  1. mf Keferi nṣegbe lọjọjọ,
    Ẹgbẹgbẹrun l’ o nkọja lọ,
    f Mura Kristian s’ igbala wọn
    Wasu fun wọn, ki nwọn to kú.

  2. f Ọrọ̀, owo, ẹ fi tọrẹ
    Na, k’ ẹ si na ki nwọn lè yè;
    Ohun ti Jesu ṣe fun nyin,
    Kil’ ẹnyin ki ba ṣe fun On? Amin.