Hymn 117: What is the cause of these wailings?

Gbo ! eredi ekun wonyi

  1. f Gbọ́ ! eredi ckun wọnyi,
    Ti a ngbọ kiri aiye?
    p Ẹkun awọn keferi ni
    Pe, “Gba wa k’ awa to.”

  2. Gb’ aroye awọn keferi,
    Kristian, gbọ́ ‘gbe ikù wọn;
    Jẹ k’ifẹ Kristi k’ o rọ̀ nyin,
    K’ẹ gbà wọn ki nwọn toku. Amin.