Anglican Hymnal
Joy to the world! The Lord is come:
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 83: Joy to the world! The Lord is come:
Ayo b’ aiye ! Oluwa de
Hymn:
83
Meter:
L.M (8.8.8.8)
Season:
Ojo Ibi Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Ayọ̀ b’ aiye! Oluwa de;
K’ aiye gbà Ọba rẹ̀;
cr
Ki gbogbo ọkàn mura de
K’ iyin kọrin soke.
f
Ayọ b’ aiye! Jesu jọba,
cr
Ẹ je k’ a ho f’ ayọ;
Gbogbo igbẹ́, omi, òkè,
Nwọn ngberin ayọ̀ na.
mf
K’ ẹ̀ṣẹ on ‘youn pin l’ aiye,
K’ ẹgún ye hù n ilẹ̀;
O de lati mu bukun ṣàn
De ‘bi t’ egún gbe de.
O f’ otọ at’ ifẹ jọba,
O jẹ k’oril’ èdè
Mọ̀ ododo ijọba Rẹ̀,
At’ ifẹ ‘yanu Rẹ̀. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites