Anglican Hymnal

THE morning bright with rosy light

Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.

Hymn 8: THE morning bright with rosy light

Imole oro, didun yi

Hymn: 8
Meter: C.M (8.6.8.6)
Season: Orin Owuro
Add Favourite
  1. Imolẹ̀ orọ̀ didun yi
    Jí mi nin’ orun mi;
    Baba, ífẹ Tirẹ nikan
    L’ o pa ọmọ Rẹ mọ.

  2. Ni gbogbo oni, mo bẹ̀ Ọ,
    Ma ṣe Oluṣọ mi;
    Darijì mi, Jesu mimọ
    Ki ‘m jẹ Tirẹ loni.

  3. Wà ṣe ‘bugbe Rẹ ninu mi,
    Ẹmi ore-ọfẹ!
    Sọ mi di mimọ laiye yi,
    K’ emi le r’oju Rẹ. Amin.