Anglican Hymnal
COME to the morning prayer
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 7: COME to the morning prayer
Wa s’ adura oro
Hymn:
7
Meter:
S.M (6.6.8.6)
Season:
Orin Owuro
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Wá s’adura orọ̀
Kunlẹ k’a gbadura:
f
Adura ni ọpa Kristian,
Lati b’ Ọlọrun rìn.
mf
Lọsan, wolẹ̀ labẹ
Apat’ aiyeraiye;
p
Itura ojiji Rẹ̀ dùn
Nigbat’ orun ba mù.
mf
Jẹ ki gbogbo ile
Wà gbadura l’ alẹ;
Ki ile wa di t’ Ọlọrun
di
Ati ‘bode ọrun.
p
Nigbat’ o d’ ọganjọ,
Jẹ k’a wi l’ẹmi, pe
Mo sùn, ṣugbọn ọkàn mi ji
Lati ba Ọ ṣọnà. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites