Anglican Hymnal
Jesus cries out that 'I am come
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 67: Jesus cries out that 'I am come
Jesu kigbe pe, “Emi de
Hymn:
67
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Bibo Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Jesu kigbe pe, “Emi de,
T’ emi ti ifẹ nla”
Ọkan mi dahun pe, “Ma bọ̀,”
K’ o mu igbala wá.
Wà, gbà ọran Baba Rẹ rò;
Si mu ogo Rẹ ràn;
f
Wá, ji okú iranṣẹ Rẹ,
K’o si sọ wọn d’ ọtun.
Ma bọ̀ wà ´larin ogun Rẹ
Lati gb’ orukọ wọn;
K’ o si m’ ajọ kikun pada
Lati y’ itẹ Rẹ ka.
Olurapada, wá kánkán,
Mu ọjọ nla ni wá.
mf
Wa, k’ ọkàn wa má bà daku,
Nitori pipẹ Rẹ. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites