Anglican Hymnal
O my brother sow a good seed
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 61: O my brother sow a good seed
Ara mi fun’ rugbin rere
Hymn:
61
Meter:
P.M (8.7.8.7.10.10)
Season:
Bibo Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Ará mi fun’ rugbin rere,
Nigba ifunrugbin wa,
Ma ṣiṣẹ l’orukọ Jesu,
Tit’ On o tun pada wá
ff
Nigbana ni a o f’ ayọ̀ ka a,
Olukore a kó wọn si abà.
f
Olugbala paṣẹ wipe,
“Ṣiṣẹ nigbat; o j’ ọsán;”
Oru mbowa,” mura giri,
Oloko fẹrẹ̀ de na
ff
Nigbana ni, &c.
T’agba t’ewe jumọ ke, pe,
“Wọ l’ oluranlọwọ wa;
Mu ni funrugbin igbagbọ,
K’a s’eso itẹwọgba.
ff
Nigbana ni, &c.
mf
Lala iṣẹ fẹrẹ̀ d’opin,
Ọwọ wa fẹ̀ ba ère;
B’o de ninu Ọlanla Rẹ̀,
Y’o sọ fun wa pe, “Ṣiwọ.”
ff
Nigbana ni a o f’ ayọ ka a,
Olukore a kó wọn si abà.
« Back to Hymn List
View Favourites