Anglican Hymnal
Come, Thou long-expected Jesus
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 59: Come, Thou long-expected Jesus
Wa iwo Jesu t’ a nreti
Hymn:
59
Meter:
8.7.8.7
Season:
Bibo Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Wá iwọ Jesu t’ a nreti
T’ a bi lati da ni n’ dè,
Gbà wa lọw’ ẹ̀ru at’ ẹ̀ṣẹ,
Jẹ k’ a ri isimi rẹ:
Iwọ ni itunu Israel,
Ireti Onigbagbọ;
Ifẹ gbogb’ orilẹ-ede
Ayọ ọkàn ti nwọ̀na.
‘Wọ t` a bi lati gbà wa là,
Ọmọ ti a bi l’Ọba;
Ti a bi lati jọba lai,
Jẹ ki ijọba Rẹ de:
Fi Ẹmi Mimọ̀ Rẹ nikan,
Ṣe akoko aiya wa;
Nipa itoye kikun Rẹ,
Gbe wa s’ori itẹ Rẹ. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites