Anglican Hymnal
Awefully miraculously
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 571: Awefully miraculously
Teruteru t’ iyanu ni
Hymn:
571
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Imo- Ohun gbogbo Olorun
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Tẹrutẹru t’ iyanu ni
Ọlọrun mi da mi,
Gbogb’ awọn ẹ̀ya ara mi,
Iṣẹ iyanu ni.
Nigbat’ a da mi n’ ikọkọ,
O ti mọ̀ ara mi;
Ẹyà ara mi l’O si mọ̀,
Sa t’ ọkan wọn kò si.
Ọlọrun, iro inu Rẹ,
Ṣe ‘yebiye fun mi;
Iye wọn pọju iyanrin,
Ti a kò lè kaye.
B’o ti mọ̀ ẹda mi bayi,
Wadi ọkàn temi;
Mu mi mọ̀ ọ̀na Rẹ lailai.
Si ma tọ́ ẹsẹ mi. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites