Anglican Hymnal
Brother, thou art/ gone be-/fore us,
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 525: Brother, thou art/ gone be-/fore us,
Ara, iwo si| waju wa lo
Hymn:
525
Meter:
P.M (Irregular)
Season:
Isinku
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mp
Ará, iwọ ṣi |waju wa lọ,
Ẹmi rẹ mi | mọ́ sì ti fò lọ,
Sibiti kò ni | s’ ẹkun mọ;
Ti | kò si irora.
O bọ́ lọwọ | ẹrù ara ---
Ati lọwọ | aniyàn aiye:
di
Nib’ ẹni-buburu | ye yọnu,
p
Ti a|larẹ̀ si simi.
mp
‘Wọ ti rìn ajò | aiye ja,
O ti | gb’ agbelebu rẹ;
cr
Krist ti fi ẹsẹ rẹ | le ọnà,
Lati | de ib’ isimi.
mp
Bi Lasaru | l’o si sùn,
L’ a|kaiya Baba rẹ,
di
Nib ẹni-buburu |ye yọnu,
p
Ti a|larẹ̀ si simi.
mf
Ẹṣẹ kò le | bà ọ jẹ́ mọ,
I|yemeji d’ opin;
Igbagbọ rẹ ni|nu Kristi
At’ Ẹmi | kò ni yẹ̀ mọ lai.
L’ ọrun lọhun | n’ iwọ o bá
Awọn ọrẹ́ | t’o ti lọ ṣaju;
di
Nib’ ẹni-buburu | ye yọnu,
p
Ti a|larẹ si simi.
Alufa ti wi ni|sisiyi pe,
mp
Eru f’eru, e|rupẹ̀ f’erupẹ;
Awa si ko e|rupẹ̀ bò ọ,
A si | samì s’orì rẹ.
cr
Ṣugbọn ẹmi rẹ | ti fò lọ,
Sọ|dọ awọn mimọ;
di
Nib’ ẹni-buburu | ye yọnu,
p
Ti a|arẹ̀ si simi.
mf
‘Gbat’ Olu|wa ba si pè
A|wa t’o kù lẹhin;
Oluwa wa, | awa bẹ̀ Ọ,
K’ai|ye má bà jẹ,
K’ olukuluku wa, b’ a|rá wa yi,
Le ri | àye lọdọ Rẹ,
di
Nib’ ẹni-buburu | ye yọnu,
p
Ti a|arẹ̀ si simi. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites