Anglican Hymnal
When Jesus left his Father's throne
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 481: When Jesus left his Father's throne
Gba Jesu f’ ite Re sile
Hymn:
481
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Orin Omode
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
‘Gba Jesu f’itẹ̀ Rẹ̀ silẹ̀,
p
O mu ‘pò irẹlẹ̀;
Ni ‘rẹlẹ̀ o mu awọ̀ wa,
pp
O wa gbé ‘nu aiye.
A ba lè rìn bi On ti rìn,
Nipa ọnà ọgbọ́n;
K’ a dagba l’ore at’ ọgbọ́n,
Bi ọdun ti npọ̀ si.
Didun l’ọ̀rọ, at’ ìwo Rẹ̀;
Gb’ awọn iyá sunmọ;
O gb ọmọ wọn s’ apa Rẹ̀,
O si sure fun wọn.
Labẹ itọju Rẹ̀, nwọn bó
Lọwọ ‘tanjẹ aiye;
Bayi ni k’awa dubulẹ̀,
Ni iṣọ oju Rẹ̀.
Gba Jesu gun kẹtẹkẹtẹ,
Awọn ‘mọde nkọrin;
f
L’ ayọ̀ nwọn ke ẹka igi,
Nwọn si tẹ ‘ṣọ silẹ.
B’ awa gbagbe ìyin Jesu,
Okuta y’o kọrin !
ff
Hosanna ni awa o kọ,
cr
Hosanna s’Ọba wa. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites