Anglican Hymnal
Tender Shepherd, Thou hast stilled
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 477: Tender Shepherd, Thou hast stilled
Odagutan, ’Wo ti re
Hymn:
477
Meter:
7.8.7.8.7.7
Season:
Orin Omode
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
Ọdagutan, ‘Wọ ti rẹ̀
p
Ọmọ Rẹ kekere l’ẹkún:
Wò b’ o ti dubulẹ jẹ
Layọ̀ ninu ibojì Rẹ̀:
Kò s’ ami irora mọ,
T’ o nyọ ọkàn Rẹ̀ lẹnu.
‘Wọ kò mu pẹ́ titi mọ
L’ aiye ẹkun on òṣi yi;
Iwọ sì f’ ayọ̀ gbà a
Si ilẹ ọrun mimọ nì;
O wọṣọ àla mimọ,
O mba Ọ gbe n’ imọlẹ.
L’ aipẹtiti, Oluwa
Mu wa de ‘bit’ ọmọ yi lọ;
Mu wa r’ ilẹ ayọ̀ na,
T’ o nf’ onjẹ ọrun bọ́ wọn:
p
B’O ti gb’ ayò wa lọ yi,
‘Gbana ao tu jere rẹ̀. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites