Anglican Hymnal
O God the throne of Thy glory
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 471: O God the throne of Thy glory
Olorun ite ogo Re
Hymn:
471
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Orin Omode
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Ọlọrun itẹ ogo Rẹ,
Yio wà titi lai;
Obi wa, talaka ni nwọn,
F’ibukun Rẹ fun wa.
O wù Ọ ni, lati ṣe wa
p
Ni talaka; ṣugbọn
Ma ṣe alabojuto wa,
‘Gba ti a wà l’aiye.
A mọ̀, b’a tilẹ jẹ Tirẹ,
T’ a j’ orukọ mọ Ọ,
A j’ alejo; ṣugbọn ṣe wa
L’ ọmọ àṣayan Rẹ.
Oluṣọ Agutan wa, wò
Agbo kekere Rẹ;
F’ọgọ at’ ọpa Rẹ tọ́ wa,
Ọmọ agb Tirẹ. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites