Anglican Hymnal
Jesus, we lift our souls to Thee;
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 453: Jesus, we lift our souls to Thee;
Jesu a gb’ okan wa si O
Hymn:
453
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Baptismu Omode
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Jesu a gb’ ọkàn wa si Ọ,
Mi Ẹmi Rẹ si wọn;
Si baptis’ ọmọde wọnyi,
Baptis’ wọn s’ikú Rẹ.
K’ ororo Rẹ wà l’ori wọn (rẹ̀),
Si tun ẹmi (rẹ̀) wọn ṣe:
Kọ orukọ Rẹ Oluwa,
Si aiya gbogbo wọn.
Ki nwọn (on) jẹ iranṣẹ Tirẹ,
K’ otọ ṣ’ àmure wọn (rẹ̀):
Ki nwọn (on) ṣ’olupin ikú Rẹ.
At’ ọmọ lẹhìn Rẹ.
Gbin gbogbo wa si ikú Rẹ,
K’a lè ni iyè Rẹ;
K’a lè gbe agbelebu Rẹ.
K’a lè ni ade Rẹ. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites