Anglican Hymnal
Jesus, thou joy of loving hearts!
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 431: Jesus, thou joy of loving hearts!
Jesu ayo okan gbogbo
Hymn:
431
Meter:
L.M (8.8.8.8)
Season:
Idapo Mimo
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Jesu ayọ̀ ọkàn gbogbo,
Orisun ‘yè, imọlẹ wa,
di
Nin’ ọpọ bukun aiye yi,
cr
Laintẹlọrùn: a tọ wá.
f
Otitọ Rẹ duro lailai,
p
‘Wọn gb’ awọn to kepè Ọ là;
cr
Awọn ti o wá Ọ, ri Ọ.
f
Bi gbogbo nin’ ohun gbogbo.
mf
A tọ Ọ wò, Onjẹ Iyè,
A fẹ jẹ l’ara Rẹ titi;
A mu ninu Rẹ, Orisun,
Lati pa ongbẹ ọkàn wa.
p
Ongbẹ Rẹ sa ngbẹ ọkàn wa,
Nibikibi t’o wù k’ a wà;
cr
‘Gbat’ a ba ri Ọ awa yọ̀,
f
A yọ̀ nigbat’ a gbà Ọ gbọ́.
mp
Jesu, wá ba wa gbe titi,
Ṣe akokò wa ni rere;
cr
Le okunkun ẹ̀ṣẹ kuro,
f
Tàn ‘mọlẹ̀ Rẹ mimọ́ s’aiye. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites