Anglican Hymnal
We adore Thee O Lord.
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 418: We adore Thee O Lord.
Awa f’ ori bale fun
Hymn:
418
Meter:
P.M (Irregular)
Season:
Ijo Olorun ni oke Orun
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Awa f’ori balẹ fun | Ọ Jesu,
‘Wọ ti ṣ’ Olori Ijọ awọn | enia Rẹ,
Ijọ ti mbẹ laiye yi, ati lọ|run pẹlu:
Alle|luya !
p
‘Wọ t’o ku, t’o sì jin|de fun wa,
T’o mbẹ lọdọ Baba bi Ala|gbawi wa,
K’ogo at’ọlanla | jẹ Tirẹ:
Alle|luya !
mf
Ati li ọjọ nla Pẹn | tikọsti,
Ti o ran Parakliti | si aiye,
Olutun nla Rẹ ti | mba wa gbe:
Alle|luya !
f
Lat’ ori itẹ Rẹ l’ o|ke ọrun,
L’O si nwò gbogbo awọn o|jiṣẹ Rẹ,
T’O si nṣikẹ gbogbo awọn Ajẹ|riku Rẹ:
Alle|luya !
f
A fi iyìn at’ ọlanla f’ o|rukọ Rẹ,
p
N’tori iku gbogbo awọn o|jiṣẹ Rẹ,
Ni gbogbo ilẹ Yo|ruba yi:
Alle|luya ! Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites