Anglican Hymnal
For all Thy saints, O Lord
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 414: For all Thy saints, O Lord
F’ awon enia Re
Hymn:
414
Meter:
S.M (6.6.8.6)
Season:
Ijo Olorun ni oke Orun
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
F’ awọn enia Rẹ,
T’o ti f’ aiye silẹè;
Awọn t’o mọ̀ Ọ, t’o sin Ọ,
Gbà orin iyìn wa.
F’ awọn enia Rẹ,
Gbà ohùn ọpẹ wa;
Awọn t’o fi Ọ s’ẹsan wọn,
f
Nwọn kú n’ igbagbo Rẹ.
mf
Ni gbogbo aiye wọn,
‘Wọ ni nwọn nwò l’oju:
Ẹmi Mimọ́ Rẹ l’o nkọ́ wọn,
Lati s’ohun gbogbo.
f
Fun eyi, Oluwa,
cr
A nyin orukọ Rẹ;
Jẹ k’a ma tẹlé iwà wọn,
di
Ki a le kù bi wọn. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites