Anglican Hymnal
PRAISE, O praise our God and King;
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 41: PRAISE, O praise our God and King;
Yin Olorun Oba wa
Hymn:
41
Meter:
7.7.7.7
Season:
Ikore
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Yin Ọlorun Ọba wa;
Ẹ gbe ohun iyin ga;
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
mf
Yin Ẹnit’ o da orùn
Ti o nràn lojojumo;
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
Ati oṣupa loru
Ti o ntanmọlẹ jẹjẹ;
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
mf
Yin Ẹnit’ o nm’ojò rọ̀
T’ o nmu irugbin dagba
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
mf
Ẹnit’ o paṣẹ fun ‘lẹ
Lati mu eso pò sí;
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
f
Yin fun ikore oko,
O mu ki àká wa kun;
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
mp
Yin f’onjẹ t’ o jù yi lọ,
Ẹri ‘bukun ailopin;
f
Anu Rẹ̀ o wa titi
Lododo dajudaju.
un
Ogo f’Ọba olore:
Ki gbogbo ẹda gberin:
Ogo fun Baba, Ọmọ,
At’ Emi: Metalọkan. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites