Anglican Hymnal
“Yet there is room”: the Lamb’s bright hall of song
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 401: “Yet there is room”: the Lamb’s bright hall of song
Aye si mbe! ile Odagutan
Hymn:
401
Meter:
10.10.10
Season:
Ikilo ati Ipe
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
“Àye ṣi mbẹ!” ile Ọdagutan,
Ẹwà ogo rẹ̀ npè ọ pe, “Ma bọ̀.”
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
Ọjọ lọ tan, orun sì fẹrẹ wọ̀,
Okunkun de tan, ‘mọlẹ nkọja lọ:
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
Ile ìyawo na kun fun àse!
f
Wọle, wọle, tọ̀ Ọkọ-‘yawo lọ:
cr
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
f
“Aye ṣi mbẹ!” ìlẹkun ṣi silẹ,
Ilẹkun ifẹ; iwọ kò pẹ jù.
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
f
Wọle! wọle! tirẹ ni àse na,
Wà gb’ẹ̀bun ‘fẹ aiyeraiye lọfẹ!
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
f
Kiki ayọ̀ l’o wà nibe; wọle!
Awọn angẹli npè ọ fun ade,
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
f
Lohùn rara n’ ipè ifẹ na ndún!
Wá, mà jafara, wọle àse na.
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
ff
O nkún! O nkún ! ile ayọ̀ na nkún !
cr
Yara ! maṣe pẹ, kò kún jù fun ọ.
p
Wọle, wọle, wọle nisisiyi.
p
K’ ilẹ to ṣu, ilẹkun na le tì!
p
‘ Gbana, o k’ abamọ́! “Oṣe ! Oṣe !”
cr
Oṣe ! Oṣe ! kò s’ àye mọ́, oṣe ! Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites