Anglican Hymnal
Happy is Sabbath day for me
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 36: Happy is Sabbath day for me
Ayo l’ ojo ’simi fun mi
Hymn:
36
Meter:
L.M (8.8.8.8)
Season:
Ojo Oluwa
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Ayọ l’ ọjọ ‘simi fun mi,
At’ agogo at’ iwasu’
p
Gbat’ a ba mi n’nu ‘banujẹ
mf
Awọn l’o nmu inu mi dun.
Ayọ̀ si ni wakati na
Ti mo lò n’nu agbala Rẹ;
Lati mọ̀ adùn adura
Lati gbà mannà ọ̀rọ Rẹ.
f
Ayọ̀ ni idahùn “Amin”
T’ o gbà gbogbo ile na kan,
Lẹkọkan l’o ndùn t’o nrọlẹ,
O nkọja lọ sọdọ Baba,
B’ aiye fẹ f’ agbara dè mi
Mọ́ iṣẹ ijọ mẹfa rẹ̀;
f
Oluwa, jọ, tù ìde na,
K’ o sọ ọkàn mi d’omnira. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites