Anglican Hymnal
O, for a faith that will not shrink
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 328: O, for a faith that will not shrink
A ba le n’igbagbo aye
Hymn:
328
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Igbagbo
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
A ba le n’igbagbọ àye,
B’o ti wù k’ọta pọ̀;
Igbagbọ ti kò jẹ mira
Fun aini at’ òṣi.
p
Igbagbọ ti kó jẹ rahùn
L’abẹ ibawi Rẹ;
cr
Ṣugbọn ti nsimi l’Ọlọrun,
Nigba ibanujẹ.
mf
Igbagbọ ti ntàn siwaju,
Gbat’ ìji ‘pọnju de;
Ti kò si jẹ ṣiyemeji,
N’nu wahala gbogbo.
Igbagbọ ti ngb’ọ̀na toro,
p
Titi ẹmi o pin;
cr
Ti y’o si f’imọlẹ ọrun,
Tàn akete iku.
mf
Jesu f’ igbagbọ yi fun mi:
Njẹ, b’o ti wù k’o ri,
cr
Lat’ aiye yilọ ngo l’ayọ
Ilu ọrun rere. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites