Anglican Hymnal
Christ Jesus, Saviour, I behold
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 314: Christ Jesus, Saviour, I behold
Jesu, Olugbala, wo mi
Hymn:
314
Meter:
8.8.8.4
Season:
Igbagbo
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
Jesu, Olugbala, wò mi,
p
Arẹ̀ mu mi, ara nni mi;
cr
Mo de lati gb’ ara le Ọ;
‘ Wọ ‘simi mi.
p
Bojuwò mi, o rẹ̀ mi tan;
Irìn àjo na gùn fun mi;
Mo nwa ‘ranwọ agbara Rẹ,
‘Wọ Ipà mi.
p
Idamu bá mi l’ọna mi,
cr
Oru ṣokùn, ìji sì nfẹ́,
Tàn imọlẹ si ọna mi,
‘Wọ ‘Mọlẹ mi.
Gba Satani ba tafà rẹ̀,
Wọ ni mo nwò; nkò bẹ̀ru mọ;
Agbelebu Rẹ l’abò mi,
‘Wọ Alafia mi.
Mo nikan wà leti Jordan,
Ninu ‘waiya-‘jà, jelo nì:
‘Wọ kì yio jẹ k’emi rì;
‘Wọ Iye mi.
Gbogbo aini, ‘Wọ o fun mi
Titi d’opin; l’ọnakọna;
Ni ‘yè, ni ‘ku, titi lailai,
‘Wọ Gbogbo mi. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites