Anglican Hymnal
Peace, perfect peace, in this dark world of sin?
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 311: Peace, perfect peace, in this dark world of sin?
Alafia, li laiye ese yi
Hymn:
311
Meter:
10.10
Season:
Igbagbo
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mp
Alafia, li aiye ẹ̀ṣẹ yi?
Ẹjẹ Jesu nwipe, “Alafia.”
mf
Alafia, ninu ọpọ lala?
Lati ṣe ifẹ Jesu, ni ‘simi.
Alafia, n’nu ìgbi banujẹ?
L’aiya Jesu ni dakẹ rọrọ wà.
mp
Alafia, gb’ ará wa wà l’ajo?
Ni ‘pamọ Jesu, ibẹru kò si.
f
Alafia, b’ a kò tilẹ m’ ọla?
Ṣugbon a mọ̀ pe Jesu wà lailai.
mp
Alafia, nigb’ akoko ikú?
f
Olugbala wa ti ṣẹgun ikú
di
O tó: jakadi aiye fẹrẹ pin,
p
Jesu y’o pe wa s’ ọrun alafia. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites