Anglican Hymnal
How shall our children and young ones
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 290: How shall our children and young ones
Bawo ni awon ewe wa
Hymn:
290
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Oro Olorun
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Bawo ni awọn èwe wa,
Y’o ti ma ṣọra wọn?
Bikoṣe “nipa ‘kiyesi,
Gẹgẹ bi ọ̀rọ Rẹ”.
‘Gba ọ̀rọ na wọ̀ ‘nu ọkàn,
A tan imọlẹ ka;
Ọ̀rọ na kọ òpe l’ ọgbọn,
At’ imọ̀ Ọlọrun.
f
Orùn ni, imọlẹ wa ni,
Amọna wa l’ọ̀sán;
Fitila ti nfọnahan wa,
Ninu ewu oru.
Ọrọ Rẹ, otọ ni titi,
Mimọ́ ni gbogbo rẹ̀;
Amọn gb l’ ọjọ ewe,
Ọpa l’ọjọ ogbó. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites