Anglican Hymnal
Almighty God of creation
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 287: Almighty God of creation
Olorun Olodumare
Hymn:
287
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Ojo Metalokan
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Ọlọrun Olodumare,
Baba, Ọmọ, Ẹmí,
Rirì ẹnit’a kò lè mọ̀,
Ẹnit’ a kò lè ri.
f
Ye! Baba Olodumare,
K’ a warìri fun Ọ;
Ni gbogbo orilẹ ede,
Li a o ma sìn Ọ.
f
Ọlọrun Ọmọ, Ọrẹ wa,
p
‘Wọ t’o rà w padda,
Má jọwọ wa, Olugbala!
Gbà wa patapata.
A ! Ọlọrun Ẹmi Mimọ́,
‘Wọ olore-ọfẹ;
A bẹ Ọ, fun wa ni imọ́,
K’ a m’Ọlọrun n’ ifẹ.
f
Ọkanṣoṣo ṣugbọn mẹta,
Ẹniu Mẹtalọkan,
Ọlọrun awamaridi,
Ẹni Mẹtalọkan !. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites