Anglican Hymnal
Give glory to the Father
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 284: Give glory to the Father
E fi ogo fun Baba
Hymn:
284
Meter:
7.7.7.7
Season:
Ojo Metalokan
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Ẹ fi ogo fun Baba,
Nipa Ẹniti a wà;
O ngbọ adura ewe,
O nf’eti si orin wọn.
f
Ẹ fi ogo fun Ọmọ,
Kristi, ‘Wọ ni Ọba wa;
ff
Ẹ wá, ẹ kọrin s’okè,
S’ Ọdagutan ẹlẹṣẹ.
f
Ogo fun Ẹmi Mimọ́,
Bi ọjọ Pentikọsti;
Rù aiya awọn ewe,
F’ orin mimọ́ s’ ète wọn
ff
Ogo ni l’oke ọrun,
Fun Ẹni Mẹtalọkan;
Nitori ihin rere,
Ati ìfẹ Ọlọrun. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites