Anglican Hymnal
To Thee, O Comforter divine
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 278: To Thee, O Comforter divine
Si O, Olutunu orun
Hymn:
278
Meter:
8.8.6
Season:
Ojo Isimi Funfun
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Si Ọ, Olutunu ọrun,
Fun ore at’ agbara Rẹ,
f
A nkọ Alleluya.
Si Ọ, ifẹ ẹnit’ o wà
Ninu majẹmu Ọlọrun,
A nkọ Alleluya.
mf
Si Ọ, Ohùn Ẹniti npè
Aṣako kuro n’nu ẹṣẹ,
f
A nkọ Alleluya.
Si Ọ, agbara Ẹniti
O nwẹ̀ ni mọ, t’o nwò ni sàn,
A nkọ Alleluya.
mf
Si Ọ, ododo Ẹniti
Gbogbo ‘leri Rẹ̀ jẹ tiwa,
f
A nkọ Alleluya.
Si Ọ, Olukọ at’ Ọrẹ,
Amọna wa totọ d’ opin,
A nkọ Alleluya.
mf
Si Ọ, Eniti Kristi ran,
f
Ade on gbòngbo ẹ̀bun Rẹ̀.
ff
A nkọ Alleluya.
f
Si Ọ, Enit’ o jẹ ọkan
Pẹlu Baba ati Ọmọ,
ff
A nkọ Alleluya. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites