Anglican Hymnal
Go tell it to all the world
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 220: Go tell it to all the world
Lo so fun gbogbo aiye
Hymn:
220
Meter:
7.7.7.7
Season:
Ajinde Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Lọ sọ fun gbogbo aiye,
cr
Lọ tan ihin ayọ̀ yi;
Eti t’ o ba gbọ́, y’o ṣi,
Ọkàn t’ o ba gbọ́, y’o là
f
Jesu Olugbala wa,
T’ a sin, fi boji silẹ̀;
Ọlọrun gba ẹbọ Rẹ̀,
Ẹbọ ẹ̀ṣẹ araiye.
mf
O ji lati má kú mọ,
Akọbi awọn t’ o sùn;
Ẹniti o ba gba gbọ
Yio ye, b’ o tilẹ kú.
mf
Angẹli ! ẹda ọrun,
f
Ẹ ba araiye gberin;
Jesu Oludande ji,
Alafia titi lai. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites