Anglican Hymnal
Dark was the night and cold the ground
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 202: Dark was the night and cold the ground
Okun l’ ale, tutu n’ ile
Hymn:
202
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Ijiya Jesu
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
APA I
p
Okùn l’ alẹ, tutù n’ilẹ,
Nibi Kristi wolẹ̀,
p
Ogùn Rẹ̀ bi iro ẹjẹ̀,
Ninu ‘wayà ija.
mf
“Baba gb’ ago kikoro yi,
B’ o ba ṣe ifẹ Rẹ;
Bi bẹkọ́, Emi o si mu,
Ifẹ Rẹ ni k’a ṣe.”
Ẹlẹṣẹ lọ wò l’ agbala,
Ẹjẹ mimọ́ wọnni:
p
O r’ ẹrù wuwo ni fun ọ,
O rẹ ‘ra ‘lẹ fun ọ.
Kọ̀ lati gbe agbelebu,
Ṣe ifẹ ti Baba;
Nigba idanwo sunmọle,
ff
Ji, ṣọra, gbadura. Amin.
APA II
p
Ki Jesu ha nikan jìya,
K’ araiye lọ lofo?
p
Iya mbẹ f’olukuluku;
cr
Iyà si mbẹ fun mi.
p
Em’ o rù agbelebu mi,
Tit’ iku y’o gbà mi;
mf
‘Gbana, ngo lọ ‘le lọ d’ ade,
‘Tor’ ade mbẹ fun mi.
f
Nilẹ ita kristali na,
Leba ẹsẹ Jesu,
f
Ngo f’ade wura mi lelẹ;
Ngo yin orukọ Rẹ̀.
f
A! agbelebu! A! ade!
cr
A! ọjọ ajinde!
Ẹnyin Angẹl, ẹ sọkalẹ,
Wá gbe ọkàn mi lọ. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites