Anglican Hymnal
From all the dangers of the night
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 2: From all the dangers of the night
Ninu gbogbo ewu oru
Hymn:
2
Meter:
C.M (8.6.8.6)
Season:
Orin Owuro
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
mf
Ninu gbogbo ewu oru,
Oluwa l’o ṣọ́ mi;
Awa si tun ri ‘mọlẹ yi
A tun tẹ ekun ba.
Oluwa, pa wa mo l’ oni,
Fi apa Rẹ ṣọ́ wa;
Kiki awọn ti ‘wọ pamọ’
L’ o nyọ ninu ewu.
K’ ọ̀rọ wa, ati ìwa wa
Wipe, Tirẹ l’awa;
Tobẹ t’ imọle otitọ
Lè tàn l’ oju aiye.
Ma jẹ k’ a pada lọdọ Rẹ,
Olugbala ọwọn;
Titi a o f’ oju wa ri
Oju Rẹ li opin. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites