Anglican Hymnal
Abundant joy who can’st recount
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 193: Abundant joy who can’st recount
Tani le so t’ayo ti mbe
Hymn:
193
Meter:
L.M (8.8.8.8)
Season:
Lenti, Isoji
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Tani le sọ t’ayọ̀ ti mbẹ
Ni àgbala Paradise;
p
Gbat’ amuṣua ba pada,
T’o si di arole ogo?
f
Ni ayọ̀ ni Baba fi wò
Eso ifẹ Rẹ̀ ailopin:
L’ayò l’Ọmọ wò ‘lẹ, t’o ri
Ere iwaya-ijà Rẹ̀.
f
Tayọtayọ̀ l’Ẹmi si nwò,
Ọkan mimọ t’ On sọ d’ọtun;
Awọn mimọ at’ Angẹl nkọ
ff
Orin igbilẹ Ọba wọn. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites