Anglican Hymnal
Jesus shall reign where e'er the sun
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 140: Jesus shall reign where e'er the sun
Jesu y’o joba ni gbogbo
Hymn:
140
Meter:
L.M (8.8.8.8)
Season:
Ifihan, Mission
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
f
Jesu y’o jọba ni gbogbo
Ibit’ a ba le ri orùn;
‘Jọba Rẹ̀ y’o tan kakiri,
‘Jọba Rẹ̀ ki o nipekun.
mf
On l’ao ma gbadura si,
Awọn ọba y’o pe l’Ọba;
Orukọ Rẹ̀ b’orùn didun,
Y’o ba ẹbọ orọ̀ goke.
Gbogbo oniruru ede,
Y’o fi ‘fẹ Rẹ̀ kọrin didun:
p
Awọn ọmọde o jẹwọ
Pe, ‘bukun wọn t’ọdọ Rẹ̀ wá.
f
‘Bukun pọ̀ nibit’ On jọba:
A tú awọn onde silẹ;
Awọn alarẹ̀ ri ‘simi;
Alaini si ri ‘bukun gbà.
ff
Ki gbogbo ẹda k’o dide,
Ki nwọn f’ọla fun Ọba wa;
K’Angẹl tun wà t’awọn t’orin,
Ki gbogb’aiye jumọ gberin. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites