Anglican Hymnal
Earth has many a noble city;
Read, listen, and switch between English and Yoruba lyrics.
All Hymns
Favourites
Hymn 124: Earth has many a noble city;
Ilu t’ o dara po l’ aiye
Hymn:
124
Meter:
8.7.8.7
Season:
Ifihan, Mission
♡
Add Favourite
Your browser does not support the audio element.
View English
Ilu t’o dara pọ̀ l’aiye;
Bẹtlẹhẹm, ‘wọ ta wọn yọ;
Ninu rẹ l’Oluwa ti wá
Lati jọba Israel.
Ogo ti irawọ ni ju
Ti orùn owurọ lọ;
Irawọ t’ o kede Jesu
Ti a bi ninu ara.
Awọn ‘lọgbọn ila-orùn
Mu ‘yebiye ọrẹ wá;
Ẹ wò, bi nwọn t fi wura,
Turari, ojia fun.
Jesu, ‘Wọ ti keferi nsin
Li ọjọ ifihan Rẹ;
Fun Ọ, Baba l’a f’ogo fun,
Ati fun Ẹmi Mimọ́. Amin.
« Back to Hymn List
View Favourites